Itan iyanu t’ife! So fun mi lekan si Itan iyanu tífe! Ti dun leti kikan Awon Angeli rohin re, awon oluso si gbagbo Elese, iwo ki yó gbo? Itan iyanu tífe! Iyanu! Iyanu! Iyanu! Itan iyanu t’ife Itan iyanu t’ife ! B’iwo tile sako Itan iyanu t’ife! Sibe o npe loni Lat’o oke kalfari, lati orisun didan ni Lati ise-dale aiye ;itan iyanu t’ife. Itan iyanu t’ife! Jesu ni isimi Itan iyanu t’ife! Fun awon oloto T’o simi n’ilu nla orun, Pel’awon to saju wa lo Nwon nko orin ayo orun, itan iyanu t’ife. Mel : John Merritte Driver 1892 [WONDERFUL STORY] Text: John Merritte Driver 1892 "Wonderful Story Of Love" Yoruba: "Itan iyanu t’ife" Web : http://www.liederschatz.net